Káàrọ̀ O-òjíire: Iṣẹ́ Ọwọ́ - Ọ̀nà Láti Borí Àìríṣẹ́ṣe
YouTubeIṣẹ́ ọwọ́ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọ̀nà pàtàkì tí ènìyàn lè gbà láti dá iṣẹ́ sílẹ̀ fún ara rẹ̀, rí owó wọlé, kí ó sì dín ìṣòro àìríṣẹ́ṣe kù láwùjọ wa. Nínú ètò yìí, a ó ṣàgbéyẹ̀wò onírúurú iṣẹ́ ọwọ́ tí ènìyàn lè kọ́, bí…


